Useful phrases in Yorùbá

A collection of useful phrases in Yorùbá. Click on the English phrases to see them in many other languages.

EnglishYorùbá
WelcomeẸ ku abọ
HelloẸ n lẹ
How are you?
I'm fine, thanks. And you?
̣Se daadaa ni o wa?
Mo wa daadaa, o ̣se. Iwọ naa n kọ?
Long time no seeO to ọjọ mẹta o / O pẹ ti a ri ara wa o
What's your name?
My name is ...
Ki ni orukọ rẹ?
Orukọ mi ni……
Where are you from?
I'm from ...
Nibo ni o ti wa?
Mo wa lati ...
Pleased to meet youInu mi dun lati mọ ọ
Good morningẸ ku aarọ
Good afternoonẸ ku ọsan
Good eveningẸ ku alẹ
Good nightO da aarọ
GoodbyeO da abọ
Good luckYoo dara o / Yoo bọ si o
Cheers/Good health!Ayọ ni o / Kara o le
Have a nice dayOni a dara o
Bon appetitOunjẹ ajẹye o / Yoo gba ibi re
Bon voyageO da abọ / Ka sọ layọ o
I don't understandKo ye emi
Please speak more slowlyJọwọ, rọra maa sọrọ
Please say that againJọwọ, tun un sọ
Please write it downJọwọ, kọ ọ silẹ
Do you speak Yorùbá?
Yes, a little
̣Se o n sọ Yorùbá?
Bẹẹ ni, diẹ
How do you say ... in Yorùbá?Bawo ni o se le sọ ….. ni Yorùbá
Excuse meẸ ̣se fun mi / Ẹ jọwọ, ẹ gbọ mi
How much is this?Eelo ni eyi?
SorryPẹlẹ
Thank you
Response
O ̣se / E se
Ko to ọpẹ
Where's the toilet?Nibo ni ile igbọnsẹ wa?
This gentleman/lady will pay for everythingAlagba/Iyaafin yii yoo sanwo fun gbogbo rẹ
Would you like to dance with me?̣Se iwọ maa ba mi jo?
I love youMo nifẹẹ rẹ
Get well soonDa ara ya o
Leave me alone!Fi mi silẹ
Help!
Fire!
Stop!
Ẹ gba mi o!
Ina o!
Duro nbẹ!
Call the police!Pe awọn ọlọpaa
Merry Christmas
and Happy New Year
Ẹ ku Ayọ Keresimesi ati Ọdun Tuntun
Happy EasterẸ ku Ayọ Ajinde
Happy BirthdayẸ ku Ayọ Ọjọ Ibi
One language
is never enough
Ede kan ko to ri rara
My hovercraft
is full of eels
Ọkọ afategun-sare mi kun fun ẹja arọ

Yorùbá phrases provided by Adedamola Olofa

If you would like to make any corrections or additions to this page, or if you can provide recordings, please contact me.

Information about Yoruba | Useful phrases in Yoruba | Tower of Babel in Yoruba | Yoruba learning materials

Links

Other collections of Yorùbá phrases
http://www.motherlandnigeria.com/languages.html
http://www.abeokuta.org/yoruba.htm

Phrases in Niger-Congo languages

Ewe, Igbo, Kinyarwanda, Lozi, Ndebele (Northern), Sesotho, Shona, Swahili, Tswana, Tumbuka, Wolof, Xhosa, Yorùbá, Zulu

Phrases in other languages