languagesoftware.net - which is the best language course or software - compare

Learn French with Frantastique

See this page
in English

Yorùbá

Yorùbá jẹ ọkan lara awọn ede mẹrin ti o se itẹwọgba ni Naijeria o si jẹ ọkan lara awọn ẹka -ede ti Naija-Kongo. Bi i miliọnu mejilelogun eniyan ni n sọ ede naa ni iwọ oorun-mọ-guusu Naijeria, orilẹ ede Benin, Togo, Ilu Ọba (UK), ati ni Amẹrika.

A kọ Yoruba fun ìgbà akọkọ ni bii igba ọdun diẹ sẹhin. Awọn atẹjade akọkọ lori Yoruba ni awọn iwe idanilẹkọ pelebe-pelebe ti a ti ọwọ John Raban kọ ni ọdun 1830 si 1832. Ẹni ti o ko ipa ti o tobi julọ si imọ-ẹkọ Yoruba ni. Bisọọbu Ajayi (Samuel) Crowther (1806 si 1891), ẹni ti o kẹkọọ nipa diẹ ninu awọn ede ti a n sọ ni Naijeria, eyi ti Yoruba jẹ ọkan ninu wọn, o kọwe, o si tun ̣se titumọ diẹ ninu wọn. Crowther tun jẹ Bisọọbu onigbagbọ akọkọ ti orirun rẹ jẹ Ìwọ-Oorun Afirika. Akọtọ Yoruba akọkọ jade ni nnkan bi i ọdun 1850, biotilẹjẹpe o ti la orisirisi iyipada kọja lati igba naa.

Alufabẹẹti/ABD Yorùbá

Alufabẹẹti/ABD Yorùbá />
</p>
<p>You can hear the sounds of the Yorùbá alphabet at:<br />
 <a href=http://www.africa.uga.edu/Yoruba/alphabet.html

Yorùbá jẹ ede olohun- ọrọ mẹta: ohun oke, ohun aarin ati ohun isalẹ. Ami ohun oke ni a n kọ bayii: (à, è, ̣è, ì, ò, ̣ò, ù). Ohun aarin kò ni ami kankan, ami fun ohun isalẹ si ni a n kọ bayii: (á, é, ̣é, í, ó, ̣ó, ú)

Download an alphabet chart for Yoruba (Excel)

Sample text

Gbogbo ènìyàn ni a bí ní òmìnira; iyì àti ẹ̀tọ́ kọ̀ọ̀kan sì dọ́gba. Wọ́n ní ẹ̀bùn ti làákàyè àti ti ẹ̀rí-ọkàn, ó sì yẹ kí wọn ó máa hùwà sí ara wọn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìyá.

Sise Itumọ

All human beings are born free and equal in dignity and rights. They are endowed with reason and conscience and should act towards one another in a spirit of brotherhood.
(Article 1 of the Universal Declaration of Human Rights)

See this page in English

Information about Yoruba | Phrases | Numbers | Telling the time | Tower of Babel | Yoruba learning materials

Links

Information about Yoruba
http://en.wikipedia.org/wiki/Yoruba_language

Online Yoruba lessons
http://mylanguages.org/yoruba_audio.php
http://www.africa.uga.edu/Yoruba/about.html
http://www.learnyoruba.com
http://polymath.org/yoruba.php

Online Yoruba dictionary
http://www.yorubadictionary.com
http://aroadeyorubadictionary.com
http://www.nigeriandictionary.com/language.php?lang_id=68&char=

Online Yoruba Radio
http://www.abeokuta.org/xtian.htm

Volta–Niger languages

Edo, Ewe, Fon, Igbo, Kupa, Yorùbá

Awon ede miiran ti a fi Latin kosile (Other languages written with the Latin alphabet)

Translated into Yorùbá by Adedamola Olofa


Cheap Web Hosting